May Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé May 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ May 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 36-37 Àwọn Ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù Hùwà Ìkà Sí I Torí Wọ́n Ń Jowú Rẹ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀? May 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 38-39 Jèhófà Ò Pa Jósẹ́fù Tì MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Sá fún Ìṣekúṣe Bíi Ti Jósẹ́fù May 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 40-41 Jèhófà Gba Jósẹ́fù Sílẹ̀ May 25-31 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 42-43 Jósẹ́fù Kó Ara Ẹ̀ Níjàánu Lọ́nà Tó Lágbára MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Fọkàn Yàwòrán Ohun Tó Ò Ń Kà