ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 May ojú ìwé 5
  • May 18-24

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • May 18-24
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 May ojú ìwé 5

May 18-24

JẸ́NẸ́SÍSÌ 40-41

  • Orin 8 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Gba Jósẹ́fù Sílẹ̀”: (10 min.)

    • Jẹ 41:9-13​—Fáráò gbọ́ nípa Jósẹ́fù (w15 2/1 14 ¶4-5)

    • Jẹ 41:16, 29-32​—Jèhófà fi ìtumọ̀ àwọn àlá Fáráò han Jósẹ́fù (w15 2/1 14-15)

    • Jẹ 41:38-40​—Jósẹ́fù di igbá kejì Fáráò Ọba Íjíbítì (w15 2/1 15 ¶2)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 41:14​—Kí nìdí tí Jósẹ́fù fi fá irun rẹ̀ kó tó lọ rí Fáráò? (w15 11/1 9 ¶1-3)

    • Jẹ 41:33​—Kí la rí kọ́ nínú ọ̀nà tí Jósẹ́fù gbà bá Fáráò sọ̀rọ̀? (w09 11/15 28 ¶14)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 40:1-23 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́​—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí ló jẹ́ ká rí i pé ọkọ àtìyàwó yìí jọ múra ìpadàbẹ̀wò náà sílẹ̀? Kí ni arákùnrin yìí ṣe kí onílé lè rí ìdí tó fi ká Ìwé Mímọ́?

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Ìpadàbẹ̀wò Àkọ́kọ́: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 13)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 128

  • Máa Fara Dà Á Tí Wọ́n Bá Hùwà Àìdáa Sí Ẹ Bíi Ti Jósẹ́fù: (6 min.) Ẹ kọ́kọ́ wo fídíò Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Máa Fara Dà Á Tí Wọ́n Bá Rẹ́ Ẹ Jẹ. Lẹ́yìn náà, pe àwọn ọmọdé mélòó kan wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n pé: Báwo ni wọ́n ṣe hùwà àìdáa sí Kọ́lá àti Tósìn? Ẹ̀kọ́ wo lo rò pé wọ́n kọ́ nínú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Jósẹ́fù?

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (9 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 19 ¶8-14

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 124 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́