ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 May ojú ìwé 6
  • May 25-31

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • May 25-31
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 May ojú ìwé 6

May 25-31

JẸ́NẸ́SÍSÌ 42-43

  • Orin 120 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jósẹ́fù Kó Ara Ẹ̀ Níjàánu Lọ́nà Tó Lágbára”: (10 min.)

    • Jẹ 42:​5-7​—Jósẹ́fù fara balẹ̀ nígbà tó rí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ (w15 5/1 13 ¶5; 14 ¶1)

    • Jẹ 42:​14-17​—Jósẹ́fù dán àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ wò (w15 5/1 14 ¶1)

    • Jẹ 42:​21, 22​—Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù fi ẹ̀mí ìrònúpìwàdà hàn (it-2 108 ¶4)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Jẹ 42:​22, 37​—Àwọn ànímọ́ tó dáa wo ni Rúbẹ́nì fi hàn? (it-2 795)

    • Jẹ 43:32​—Kí nìdí táwọn ará Íjíbítì fi kà á sóhun ìríra láti bá àwọn Hébérù jẹun? (w04 1/15 29 ¶2)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 42:​1-20 (th ẹ̀kọ́ 2)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì​—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà bi wọ́n pé: Báwo ni arákùnrin yìí ṣe nasẹ̀ Ìwé Mímọ́ lọ́nà tó yẹ? Kí nìdí tí arákùnrin náà fi lo ìwé Bíbélì Kọ́ Wa? Báwo ló sì ṣe nasẹ̀ rẹ̀?

  • Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 15)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 34 ¶18 (th ẹ̀kọ́ 8)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 94

  • “Máa Fọkàn Yàwòrán Ohun Tó Ò Ń Kà”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Mú Kí Bó O Ṣe Ń Ka Bíbélì Sunwọ̀n Sí I​—Àyọlò. Gba àwọn ará níyànjú láti wo fídíò náà látìbẹ̀rẹ̀ dópin.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 19 ¶15-19

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 79 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́