June 1-7
JẸ́NẸ́SÍSÌ 44-45
Orin 130 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jósẹ́fù Dárí Ji Àwọn Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀”: (10 min.)
Jẹ 44:1, 2—Jósẹ́fù dán àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ wò (w15 5/1 14-15)
Jẹ 44:33, 34—Júdà bẹ Jósẹ́fù pé kó dá Bẹ́ńjámínì sílẹ̀
Jẹ 45:4, 5—Jósẹ́fù fara wé Jèhófà ní ti bó ṣe dárí ji àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Jẹ 44:13—Kí ló túmọ̀ sí tẹ́nì kan bá fa aṣọ rẹ̀ ya? (it-2 813)
Jẹ 45:5-8—Kí ló lè ràn wá lọ́wọ́ láti fara dà á tí wọ́n bá hùwà àìdáa sí wa? (w04 8/15 15 ¶15)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 45:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Jẹ́ Kí Àwọn Èèyàn Rí Ẹ̀kọ́ Kọ́ Nínú Ọ̀rọ̀ Rẹ, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 18 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w06 2/1 31—Àkòrí: Ṣé Jósẹ́fù máa ń lo ife fàdákà tó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀ kan láti fi woṣẹ́, bó ṣe jọ pé Jẹ́nẹ́sísì 44:5, 15 sọ? (th ẹ̀kọ́ 18)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 19 ¶20-23
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 19 àti Àdúrà