June Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé June 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ June 1-7 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 44-45 Jósẹ́fù Dárí Ji Àwọn Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀ June 8-14 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 46-47 Jèhófà Pèsè Oúnjẹ Lásìkò Ìyàn June 15-21 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 48-50 Àwọn Àgbàlagbà Ní Ohun Púpọ̀ Láti Kọ́ Wa MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀kọ́ Wo Ló Lè Kọ́ Lára Àwọn Kristẹni Tó Nírìírí? June 22-28 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 1-3 “Èmi Yóò Di Ohun Tí Mo Bá Fẹ́” June 29–July 5 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 4-5 “Màá Wà Pẹ̀lú Rẹ Bí O Ṣe Ń Sọ̀rọ̀” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bá A Ṣe Lè Lo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI O Lè Wàásù Kó O sì Máa Kọ́ni!