June 29–July 5
Ẹ́KÍSÓDÙ 4-5
Orin 3 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Màá Wà Pẹ̀lú Rẹ Bí O Ṣe Ń Sọ̀rọ̀”: (10 min.)
Ẹk 4:10, 13—Mósè ronú pé òun ò kúnjú ìwọ̀n fún iṣẹ́ tí Jèhófà fún òun (w10 10/15 13-14)
Ẹk 4:11, 12—Jèhófà fi í lọ́kàn balẹ̀ (w14 4/15 9 ¶5-6)
Ẹk 4:14, 15—Jèhófà ṣètò pé kí Áárónì ran Mósè lọ́wọ́ (w10 10/15 14)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Ẹk 4:24-26—Kí ló ṣeé ṣe kó fà á tí Sípórà fi sọ nípa Jèhófà pé “ọkọ ẹlẹ́jẹ̀ lo jẹ́ fún mi”? (w04 3/15 28 ¶4)
Ẹk 5:2—Kí ni Fáráò ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé òun kò mọ Jèhófà? (it-2 12 ¶5)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 4:1-17 (th ẹ̀kọ́ 12)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, pe ẹni náà wá sí àwọn ìpàdé wa. (th ẹ̀kọ́ 2)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ wa. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 100 ¶15-16 (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Bá A Ṣe Lè Lo Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ”: (5 min.) Ìjíròrò.
“O Lè Wàásù Kó O sì Máa Kọ́ni!”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ẹ Jẹ́ Onígboyà . . . Ẹ̀yin Akéde.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) jy orí 121
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 73 àti Àdúrà