ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 June ojú ìwé 6
  • “Èmi Yóò Di Ohun Tí Mo Bá Fẹ́”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Èmi Yóò Di Ohun Tí Mo Bá Fẹ́”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Nǹkan Tó Rọ̀ Mọ́ Mímọ Orúkọ Ọlọ́run
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
  • Ọkùnrin àti Obìnrin Ọlọ́run Dá Wọn Láti Ṣàlékún Ara Wọn
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • “Wò Ó! Ọlọ́run Wa Nìyí!”
    Sún Mọ́ Jèhófà
  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ẹ Jẹ́ Kí Òtítọ́ Jinlẹ̀ Nínú Yín
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 June ojú ìwé 6
Mósè kúnlẹ̀, ó sì yí ojú rẹ̀ kúrò lára igbó tó ń jó.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 1-3

“Èmi Yóò Di Ohun Tí Mo Bá Fẹ́”

3:13, 14

Jèhófà jẹ́ kí Mósè mọ apá pàtàkì kan lára irú ẹni tóun jẹ́. Jèhófà lè di ohunkóhun lábẹ́ ipò èyíkéyìí láti mú ohun tó ní lọ́kàn ṣẹ, síbẹ̀ kì í tẹ ìlànà ìdájọ́ òdodo rẹ̀ lójú. Bíi táwọn òbí wa, Jèhófà lè di ohunkóhun tó yẹ láti bójú tó àwọn ọmọ rẹ̀.

Àwọn nǹkan wo ni Jèhófà ti dì láti ràn mí lọ́wọ́?

Àwòrán: Bàbá kan ń fìfẹ́ hàn sí ìdílé rẹ̀ lóríṣiríṣi ọ̀nà. 1. Òun àti ọmọkùnrin rẹ̀ kọ́kọ́ jọ sọ̀rọ̀, lẹ́yìn náà ó bá a tẹ́ aṣọ bẹ́ẹ̀dì rẹ̀ dáadáa. 2. Ó ka ẹsẹ ojoojúmọ́ pẹ̀lú ìyàwó àti ọmọkùnrin rẹ̀. 3. Ó kọ́ ọmọkùnrin rẹ̀ bí wọ́n ṣe ń gun kẹ̀kẹ́.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́