ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 August ojú ìwé 7
  • August 24-30

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 24-30
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 August ojú ìwé 7

August 24-30

Ẹ́KÍSÓDÙ 19-20

  • Orin 88 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ̀kọ́ Tí Òfin Mẹ́wàá Náà Kọ́ Wa Lónìí”: (10 min.)

    • Ẹk 20:​3-7​—Bọlá fún Jèhófà, kó o sì máa jọ́sìn òun nìkan (w89 11/15 6 ¶1)

    • Ẹk 20:​8-11​—Ìjọsìn Jèhófà ni kó ṣe pàtàkì jù lọ láyé rẹ

    • Ẹk 20:​12-17​—Máa bọlá fáwọn míì (w89 11/15 6 ¶2-3)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 19:​5, 6​—Kí nìdí tí orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì àtijọ́ fi pàdánù àǹfààní tí wọ́n ní láti di “ìjọba àwọn àlùfáà”? (it-2 687 ¶1-2)

    • Ẹk 20:​4, 5​—Báwo ni Jèhófà ṣe ń “fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ àwọn bàbá” jẹ àwọn àtọmọdọ́mọ wọn? (w04 3/15 27 ¶1)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 19:​1-19 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fún onílé ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 1)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 15)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 67-68 ¶17-19 (th ẹ̀kọ́ 8)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 91

  • Kí Ni Mo Lè Ṣe Kí N Lè Túbọ̀ Lómìnira?: (6 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò eré ojú pátákó náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ọ̀dọ́ pé: Kí lo lè ṣe káwọn òbí ẹ lè fọkàn tán ẹ? Kí ló yẹ kó o ṣe tó o bá ṣàṣìṣe? Tó o bá ń bọ̀wọ̀ fáwọn òbí ẹ, báwo nìyẹn ṣe máa jẹ́ kí wọ́n túbọ̀ fún ẹ lómìnira?

  • Máa Tọ́jú Àwọn Òbí Ẹ Àgbà: (9 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé: Àwọn ìṣòro wo ló lè yọjú báwọn òbí ṣe túbọ̀ ń dàgbà? Kí nìdí tó fi yẹ káwọn tó wà nínú ìdílé jọ sọ̀rọ̀ dáadáa tí wọ́n bá fẹ́ pinnu bí wọ́n á ṣe tọ́jú àwọn òbí wọn? Báwo làwọn ọmọ ṣe lè bọlá fáwọn òbí wọn tí wọ́n ń tọ́jú?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) jy orí 129 àti àpótí “Bí Wọ́n Ṣe Máa Ń Na Ọ̀daràn”

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 13 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́