August Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé August 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ August 3-9 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 13-14 “Ẹ Dúró Gbọn-in, Kí Ẹ sì Rí Bí Jèhófà Ṣe Máa Gbà Yín Là” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ Dúró Gbọn-in Bí Òpin Ṣe Ń Sún Mọ́lé August 10-16 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 15-16 Máa Fi Orin Yin Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Fi Iṣẹ́ Aṣáájú-Ọ̀nà Yin Jèhófà August 17-23 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 17-18 Àwọn Tó Lẹ́mìí Ìrẹ̀lẹ̀ Máa Ń Faṣẹ́ Lé Àwọn Míì Lọ́wọ́ August 24-30 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 19-20 Ẹ̀kọ́ Tí Òfin Mẹ́wàá Náà Kọ́ Wa Lónìí August 31–September 6 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 21-22 Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Jọ Ẹ́ Lójú Bíi Ti Jèhófà