August 3-9
Ẹ́KÍSÓDÙ 13-14
Orin 148 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Dúró Gbọn-in, Kí Ẹ sì Rí Bí Jèhófà Ṣe Máa Gbà Yín Là”: (10 min.)
Ẹk 14:13, 14—Mósè nígbàgbọ́ pé Jèhófà máa gba àwọn ọmọ Ísírẹ́lì là (w13 2/1 4)
Ẹk 14:21, 22—Jèhófà gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́nà ìyanu (w18.09 26 ¶13)
Ẹk 14:26-28—Jèhófà pa Fáráò àtàwọn ọmọ ogun ẹ̀ run (w09 3/15 7 ¶2-3)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Ẹk 13:17—Báwo ni Jèhófà ṣe gba tàwọn ọmọ Ísírẹ́lì rò nígbà tó mú wọn jáde kúrò ní Íjíbítì? (it-1 1117)
Ẹk 14:2—Ibo ló ṣeé ṣe kí Òkun Pupa ti pín yà káwọn ọmọ Ísírẹ́lì lè sọdá? (it-1 782 ¶2-3)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 13:1-20 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Tẹra Mọ́ Kíkàwé àti Kíkọ́ni: (10 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Ìparí Ọ̀rọ̀ Tó Dára, lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ 20 nínú ìwé pẹlẹbẹ Kíkọ́ni.
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w07 12/15 18-20 ¶13-16—Àkòrí: Kí La Rí Kọ́ Nínú Bí Ọlọ́run Ṣe Gba Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Là ní Òkun Pupa? (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ Dúró Gbọn-in Bí Òpin Ṣe Ń Sún Mọ́lé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àwọn Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú Tó Gba Pé Ká Ní Ìgboyà—Àyọlò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) jy orí 126
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 128 àti Àdúrà