Mósè na ọ̀pá rẹ̀ sókè láti pín Òkun Pupa níyà
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo làwọn tó ń ṣọ̀fọ̀ ṣe lè rí ìtùnú?
Bíbélì: 2Kọ 1:3, 4
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sẹ́ni tó bá kú?
○● ÌPADÀBẸ̀WÒ
Ìbéèrè: Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sẹ́ni tó bá kú?
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ìrètí wo ló wà fún àwọn tó ti kú?