MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
Nígbà Àkọ́kọ́
Ìbéèrè: Kí ni Ọlọ́run fẹ́ fún àwa èèyàn?
Bíbélì: Jẹ 1:28
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn fún wa?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:
Ìpadàbẹ̀wò
Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn fún wa?
Bíbélì: Ais 55:11
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ayé ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá ṣe ohun tó ní lọ́kàn?
WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: