May Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, May-June 2021 May 3-9 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Yẹra fún Ojúsàájú, Kó O Lè Fìwà Jọ Jèhófà May 10-16 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN San Ẹ̀jẹ́ Rẹ May 17-23 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Ẹ Lé Gbogbo Àwọn Tó Ń Gbé Ilẹ̀ Náà Kúrò” MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Máa Fi Àpèjúwe Ṣàlàyé Kókó Pàtàkì May 24-30 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Fi Jèhófà Ṣe Ibi Ààbò Rẹ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ìfẹ́ Ló Ń Mú Kí Jèhófà Bá Wa Wí May 31–June 6 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Ọlọ́run Ló Ni Ìdájọ́” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Múra Sílẹ̀ Ní Apá Ìgbẹ̀yìn “Àwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn” Yìí June 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Àwọn Òfin Jèhófà Bọ́gbọ́n Mu, Wọ́n sì Bá Ìdájọ́ Òdodo Mu MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Máa Lo Ìtara Tó O Bá Ń Kọ́ni June 14-20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Fìfẹ́ Hàn Nínú Ìdílé June 21-27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “O Ò Gbọ́dọ̀ Bá Wọn Dána Rárá” June 28–July 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Kí Ni Jèhófà Ọlọ́run Rẹ Fẹ́ Kó O Ṣe?” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu Lórí Ọ̀rọ̀ Ọtí MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ