May 17-23
NỌ́ŃBÀ 32-33
Orin 142 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ẹ Lé Gbogbo Àwọn Tó Ń Gbé Ilẹ̀ Náà Kúrò”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Nọ 33:54—Báwo ni wọ́n ṣe pín ilẹ̀ fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì? (it-1 359 ¶2)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 32:28-42 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Fi Àpèjúwe Ṣàlàyé Kókó Pàtàkì”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Túbọ̀ Já Fáfá—Máa Fi Àpèjúwe Ṣàlàyé Kókó Pàtàkì.
Àsọyé: (5 min.) w09 10/1 30, àpótí—Àkòrí: Kí Nìdí Tí Jèhófà Fi Fọwọ́ Sí I Pé Káwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Jagun Láyé Àtijọ́? (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 8 ¶23-27 àti àpótí 8B
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 107 àti Àdúrà