June 21-27
DIUTARÓNÓMÌ 7-8
Orin 136 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“O Ò Gbọ́dọ̀ Bá Wọn Dána Rárá”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Di 8:3—Kí la rí kọ́ látinú bí Jèhófà ṣe pèsè mánà fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì? (w04 2/1 13 ¶4)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 7:1-16 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Pe ẹni náà wá sípàdé. (th ẹ̀kọ́ 15)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 9)
Àsọyé: (5 min.) w06 1/1 28 ¶14-15—Àkòrí: Má Ṣe Gbàgbé Jèhófà. (th ẹ̀kọ́ 7)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù June.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 9 ¶33-39 àti àpótí 9Ẹ
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 145 àti Àdúrà