ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 May ojú ìwé 15
  • June 28–July 4

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 28–July 4
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 May ojú ìwé 15

June 28–July 4

DIUTARÓNÓMÌ 9-10

  • Orin 49 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Kí Ni Jèhófà Ọlọ́run Rẹ Fẹ́ Kó O Ṣe?”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Di 9:1-3​—Bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn ọmọ Ánákì ‘tóbi, tí wọ́n sì ga,’ kí nìdí tí kò fi yẹ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì bẹ̀rù wọn? (it-1 103)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 10:1-22 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) fg ẹ̀kọ́ 12 ¶4-5 (th ẹ̀kọ́ 18)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 135

  • Kí Ni Géèmù Tó Ò Ń Gbá Ń Sọ Nípa Ẹ?: (7 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà béèrè pé: Kí ló lè ṣẹlẹ̀ sí ẹ tó o bá jẹ́ kí géèmù di bárakú fún ẹ? Àwọn nǹkan wo ló ṣe pàtàkì ju géèmù lọ? (Ef 5:​15, 16) Kí nirú géèmù tó ò ń gbá ń sọ nípa ẹ? Ọ̀nà wo ló dáa jù tó o lè gbà lo àkókò ẹ?

  • “Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu Lórí Ọ̀rọ̀ Ọtí”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọtí Di Ìdẹkùn fún Ẹ.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 10 ¶1-7 àti fídíò ohun tó wà ní orí 10

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 3 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́