ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 May ojú ìwé 2
  • May 3-9

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • May 3-9
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 May ojú ìwé 2

May 3-9

NỌ́ŃBÀ 27-29

  • Orin 106 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Yẹra fún Ojúsàájú, Kó O Lè Fìwà Jọ Jèhófà”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Nọ 28:7, 14​—Kí ni ọrẹ ohun mímu? (it-2 528 ¶5)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 28:​11-31 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Ohun Tí Ọlọ́run Fẹ́ fún Wa​—Jẹ 1:28. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Àsọyé: (5 min.) w07 4/1 17-18​—Àkòrí: Kí Lá Mú Kínú Jèhófà Dùn sí Ọrẹ Tàbí Ẹbọ Wa? (th ẹ̀kọ́ 16)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 82

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Nífẹ̀ẹ́ Ọmọnìkejì Rẹ: (6 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, tó bá ṣeé ṣe, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan, kó o sì béèrè àwọn ìbéèrè yìí lọ́wọ́ wọn: Kí nìdí táwọn ọmọléèwé ò fi gba ti Priya? Báwo ni Tósìn ṣe fìfẹ́ hàn sí Priya? Báwo lo ṣe lè fìfẹ́ hàn sáwọn tí àwọ̀ tàbí èdè wọn yàtọ̀ sí tìẹ?

  • Ta Ni Ọ̀rẹ́ Tòótọ́?: (9 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò eré ojú pátákó náà. Lẹ́yìn náà béèrè pé: Kí ló yẹ kó o wò lára ẹni tó o fẹ́ fi ṣọ̀rẹ́? Ibo lo ti lè rí ọ̀rẹ́ gidi? Báwo lo ṣe lè ní ọ̀rẹ́ gidi?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 8 ¶8-15 àti àpótí 8A

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 16 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́