ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 May ojú ìwé 1
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
  • ○●○ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
  • ○○●ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 May ojú ìwé 1
Jósẹ́fù wà lẹ́wọ̀n ní Íjíbítì.

Jósẹ́fù gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà nígbà tó wà lẹ́wọ̀n ní Íjíbítì

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ló ń ṣẹlẹ̀ sẹ́ni tó ti kú?

Bíbélì: Onw 9:5a

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ṣé ìrètí wà fún àwọn tó ti kú?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?’

    bhs 63 ¶6

○●○ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Ṣé ìrètí wà fún àwọn tó ti kú?

Bíbélì: Job 14:14, 15

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ló ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá jí àwọn èèyàn wa tó ti kú dìde?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?’

    bhs 76 ¶14

○○●ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Báwo ló ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá jí àwọn èèyàn wa tó ti kú dìde?

Bíbélì: Ais 32:18

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa mú kí àlàáfíà jọba láyé yìí?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?’

    bhs 35 ¶18

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́