ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 April ojú ìwé 1
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
  • ○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
  • ○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
  • ÌKÉSÍNI SÍ ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (March 14–April 7):
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 April ojú ìwé 1
Jésù àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ olóòótọ́ jọ jókòó pa pọ̀ láti jẹ Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa.

Jésù bá àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ olóòótọ́ dá májẹ̀mú

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ni Ọlọ́run fẹ́ fún àwa èèyàn?

Bíbélì: Jẹ 1:28

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn fún wa?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?’

    bhs 29 ¶1

○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run máa ṣe ohun tó ní lọ́kàn fún wa?

Bíbélì: Ais 55:11

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ni ayé ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá ṣe ohun tó ní lọ́kàn?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?’

    bhs 29 ¶2

○○● ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ

Ìbéèrè: Báwo ni ayé ṣe máa rí nígbà tí Ọlọ́run bá ṣe ohun tó ní lọ́kàn?

Bíbélì: Sm 37:10, 11

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí la gbọ́dọ̀ ṣe ká tó lè gbádùn àwọn ìlérí Ọlọ́run yẹn?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?’

    bhs 35 ¶17

ÌKÉSÍNI SÍ ÌRÁNTÍ IKÚ KRISTI (March 14–April 7):

O lè sọ pé: “A fẹ́ pè yín síbi Ìrántí Ikú Kristi tá a máa ń ṣe lọ́dọọdún. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ṣe ìpàdé pàtàkì yìí kárí ayé.” Fún ẹni náà ní ìwé ìkésíni, kó o wá sọ pé: “Ìwé ìkésíni yìí máa jẹ́ kẹ́ ẹ mọ ibi tá a ti fẹ́ ṣe é ládùúgbò wa àti àkókò tó máa bẹ̀rẹ̀. A tún fẹ́ kẹ́ ẹ wá gbọ́ àkànṣe àsọyé kan ní ọ̀sẹ̀ tó ṣáájú Ìrántí Ikú Kristi náà.”

Tí Ẹni Náà Bá Nífẹ̀ẹ́ Sí Ọ̀rọ̀ Rẹ, Fi Ìbéèrè Yìí Sílẹ̀: Kí nìdí tí Jésù fi kú?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́