ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 16
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi (February 27–March 27)
  • Nígbà Àkọ́kọ́
  • Ìpadàbẹ̀wò
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 16

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìkésíni sí Ìrántí Ikú Kristi (February 27–March 27)

Ìwé ìkésíni sí Ìrántí Ikú Jésù, àkòrí ẹ̀ ni ‘A Fẹ́ Kí O Wá!’

O lè sọ pé: “A fẹ́ pè yín síbi Ìrántí Ikú Kristi tá a máa ń ṣe lọ́dọọdún [o lè pè lórí fóònù tàbí kó o fọ̀rọ̀ ránṣẹ́]. Ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ṣe ìpàdé pàtàkì yìí kárí ayé.” Fún ẹni náà ní ìwé ìkésíni [tàbí kó o fi ránṣẹ́ lórí ìkànnì], kó o wá sọ pé: “Ìwé ìkésíni yìí máa jẹ́ kẹ́ ẹ mọ ibi tá a ti fẹ́ ṣe é ládùúgbò wa [tàbí bẹ́ ẹ ṣe lè wò ó lórí ìkànnì] àti àkókò tó máa bẹ̀rẹ̀. A tún fẹ́ kẹ́ ẹ wá gbọ́ àkànṣe àsọyé kan ní ọ̀sẹ̀ tó ṣáájú Ìrántí Ikú Kristi náà.”

Tí Ẹni Náà Bá Nífẹ̀ẹ́ sí Ọ̀rọ̀ Rẹ: Fi fídíò Ìrántí Ikú Jésù hàn án [tàbí kó o fi ránṣẹ́ sí i lórí ìkànnì].

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tí Jésù fi kú?

Nígbà Àkọ́kọ́

Ìbéèrè: Ta ni Jésù?

Bíbélì: Mt 16:16

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí nìdí tí Jésù fi kú?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?’

    bhs 41 ¶5

Ìpadàbẹ̀wò

Ìbéèrè: Kí nìdí tí Jésù fi kú?

Bíbélì: Mt 20:28

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì bí Jésù ṣe kú fún wa?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

  • Ìwé ‘Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?’

    bhs 52 ¶2

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́