September 7-13
Ẹ́KÍSÓDÙ 23-24
Orin 34 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Má Ṣe Tẹ̀ Lé Ọ̀pọ̀ Èèyàn”: (10 min.)
Ẹk 23:1—O ò gbọ́dọ̀ tan ìròyìn èké kálẹ̀ (w18.08 4 ¶7-8)
Ẹk 23:2—O ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ọ̀pọ̀ èèyàn láti hùwà ibi (it-1 11 ¶3)
Ẹk 23:3—O ò gbọ́dọ̀ ṣe ojúsàájú (it-1 343 ¶5)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Ẹk 23:9—Kí ni Jèhófà sọ fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì kí wọ́n lè máa fàánú hàn sáwọn àjèjì? (w16.10 9 ¶4)
Ẹk 23:20, 21—Ẹ̀rí wo ló fi hàn pé Máíkẹ́lì ni áńgẹ́lì yìí? (it-2 393)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 23:1-19 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè pé: Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìdáhùn onílé yẹn ò tọ̀nà, báwo ni akéde yìí ṣe wá ibi tọ́rọ̀ òun àti onílé ti jọra kó lè bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀ ẹ̀ níbẹ̀? Ọ̀nà wo ni akéde yìí tún lè gbà lo Ilé Ìṣọ́ No. 3 2020?
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 1)
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w16.05 30-31—Àkòrí: Báwo ni Kristẹni kan ṣe máa mọ̀ bóyá ó tọ́ kí òun fún òṣìṣẹ́ ìjọba kan ní owó tàbí ẹ̀bùn? (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ṣọ́ra Kó O Má Bàa Tan Irọ́ Kálẹ̀”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò eré ojú pátákó náà Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Òfófó?
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 131
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 145 àti Àdúrà