September Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé September 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ September 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 23-24 Má Ṣe Tẹ̀ Lé Ọ̀pọ̀ Èèyàn MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣọ́ra Kó O Má Bàa Tan Irọ́ Kálẹ̀ September 14-20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 25-26 Ohun Tó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ Nínú Àgọ́ Ìjọsìn September 21-27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 27-28 Ohun Tá A Rí Kọ́ Nípa Aṣọ Àlùfáà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Fi Fóònù Tàbí Kámẹ́rà Wàásù September 28–October 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 29-30 Wọ́n Mú Ọrẹ Wá fún Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé O Lè Lo Àkókò àti Okun Rẹ?