ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 September ojú ìwé 4
  • September 14-20

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • September 14-20
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 September ojú ìwé 4

September 14-20

Ẹ́KÍSÓDÙ 25-26

  • Orin 18 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ohun Tó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ Nínú Àgọ́ Ìjọsìn”: (10 min.)

    • Ẹk 25:9​—Jèhófà sọ bí wọ́n ṣe máa kọ́ àpótí májẹ̀mú (it-1 165)

    • Ẹk 25:21​—Inú àpótí yẹn ni ibi mímọ́ tí wọ́n tọ́jú “Òfin Mẹ́wàá” sí (it-1 166 ¶2)

    • Ẹk 25:22​—Àpótí náà ń jẹ́ kí wọ́n mọ̀ pé Ọlọ́run wà láàárín wọn (it-1 166 ¶3)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 25:20​—Kí ló ṣeé ṣe kó mú kí wọ́n gbé àwọn kérúbù yẹn síbi tí wọ́n gbé wọn sí lórí Àpótí? (it-1 432 ¶1)

    • Ẹk 25:30​—Kí ni búrẹ́dì àfihàn? (it-2 936)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 25:​23-40 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè pé: Báwo ni akéde yẹn ṣe fi ọ̀yàyà hàn, tó sì fi hàn pé òun fi ọ̀rọ̀ ro ara òun wò? Ọ̀nà wo ni akéde yẹn tún lè gbà lo Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́?

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 8)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 23

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù September.

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 132, àti àpótí “Kàn án Mọ́gi”

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 20 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́