September 28–October 4
Ẹ́KÍSÓDÙ 29-30
Orin 32 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Wọ́n Mú Ọrẹ Wá fún Jèhófà”: (10 min.)
Ẹk 30:11, 12—Jèhófà ní kí Mósè ka iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (it-2 764-765)
Ẹk 30:13-15—Gbogbo àwọn tó forúkọ sílẹ̀ mú ọrẹ wá fún Jèhófà (it-1 502)
Ẹk 30:16—Wọ́n lo ọrẹ náà “fún iṣẹ́ àgọ́ ìpàdé” (w11 11/1 12 ¶1-2)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Ẹk 29:10—Kí ló túmọ̀ sí tàwọn àlùfáà bá “gbé ọwọ́ wọn lé orí akọ màlúù”? (it-1 1029 ¶4)
Ẹk 30:31-33—Kí nìdí tí wọ́n fi gbọ́dọ̀ pa ẹnikẹ́ni tó bá ṣe òróró àfiyanni mímọ́, tó sì fi pa ẹni tí kò tọ́ lára? (it-1 114 ¶1)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 29:31-46 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ, kó o sì bá ẹni náà sọ̀rọ̀ látorí fóònù tàbí kó o lo kámẹ́rà. (Tí kò bá ṣeé ṣe ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín, ṣe bíi pé ò ń wàásù fún ẹni kan tó wà nínú ilé, àmọ́ tí kò ṣí ilẹ̀kùn fún ẹ.) (th ẹ̀kọ́ 2)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 113 ¶18 (th ẹ̀kọ́ 13)
Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) km 1/11 4 ¶5-7; 6, àpótí—Àkòrí: Àwọn Nǹkan Tẹ́ Ẹ Lè Ṣe Nígbà Ìjọsìn Ìdílé Yín. (th ẹ̀kọ́ 20)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ṣé O Lè Lo Àkókò àti Okun Rẹ?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà À Ń Múra Sílẹ̀ Láti Kọ́ Ilé Tuntun—Àyọlò.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 134
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 137 àti Àdúrà