September 21-27
Ẹ́KÍSÓDÙ 27-28
Orin 25 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ohun Tá A Rí Kọ́ Nípa Aṣọ Àlùfáà”: (10 min.)
Ẹk 28:36—A gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́ nígbà gbogbo (it-1 849 ¶3)
Ẹk 28:42, 43—A gbọ́dọ̀ máa sá fún ohun tó máa tàbùkù sí orúkọ Jèhófà (w08 8/15 15 ¶17)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Ẹk 28:15-21—Ibo ni wọ́n ti rí àwọn òkúta iyebíye tó wà lára aṣọ ìgbàyà àlùfáà àgbà ní Ísírẹ́lì? (w12 8/1 26 ¶1-3)
Ẹk 28:38—Kí ni “àwọn ohun mímọ́”? (it-1 1130 ¶2)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 27:1-21 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 2)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 93 ¶20-21 (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Fi Fóònù Tàbí Kámẹ́rà Wàásù”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò 1 kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀, lẹ́yìn náà ẹ wo fídíò 2 kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 133
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 46 àti Àdúrà