ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 October ojú ìwé 6
  • October 19-25

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 19-25
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 October ojú ìwé 6

October 19-25

Ẹ́KÍSÓDÙ 35-36

  • Orin 92 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Ràn Wọ́n Lọ́wọ́ Láti Ṣe Iṣẹ́ Rẹ̀”: (10 min.)

    • Ẹk 35:​25, 26​—Jèhófà máa ń bù kún àwọn tó bá múra tán láti ṣe iṣẹ́ rẹ̀ (w14 12/15 4 ¶4)

    • Ẹk 35:​30-35​—Ẹ̀mí mímọ ran Bẹ́sálẹ́lì àti Òhólíábù lọ́wọ́ kí wọ́n lè ṣe “onírúurú iṣẹ́” (w11 12/15 18 ¶6)

    • Ẹk 36:​1, 2​—Jèhófà ló ràn wọ́n lọ́wọ́ láti ṣe iṣẹ́ náà (w11 12/15 19 ¶7)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 35:​1-3​—Kí la lè rí kọ́ nípa bí Jèhófà ṣe fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lófin nípa Sábáàtì? (w05 5/15 23 ¶14)

    • Ẹk 35:21​—Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nípa bí wọ́n ṣe jẹ́ ọ̀làwọ́? (w00 11/1 29 ¶1)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 35:​1-24 (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 11)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ fún onílé pé kó lọ sórí ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 26 ¶18-20 (th ẹ̀kọ́ 19)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 68

  • Ìròyìn Ìgbìmọ̀ Ìṣèwéjáde ti Ọdún 2018: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà béèrè pé: Àwọn àyípadà wo la ti ṣe sí bá a ṣe ń tẹ ìwé jáde, kí sì nìdí tá a fi ṣe bẹ́ẹ̀? Kí ni àbájáde àwọn àyípadà yìí? Báwo ni iṣẹ́ ìtúmọ̀ èdè ṣe ń mú kí ọ̀pọ̀ èèyàn túbọ̀ rí oúnjẹ tẹ̀mí? Àwọn ìbùkún wo là ń rí bá a ṣe ń gbé àwọn ìtẹ̀jáde wa sórí ìkànnì?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 137

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 69 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́