October Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé October 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ October 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 31-32 Ẹ Sá fún Ìbọ̀rìṣà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mọyì Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Jèhófà October 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 33-34 Àwọn Ànímọ́ Jèhófà Tó Fani Mọ́ra MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ṣé Jèhófà Ni Ọ̀rẹ́ Tẹ́ Ẹ Fẹ́ràn Jù Lọ? October 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 35-36 Jèhófà Ràn Wọ́n Lọ́wọ́ Láti Ṣe Iṣẹ́ Rẹ̀ October 26–November 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 37-38 Ohun Tí Pẹpẹ Àgọ́ Ìjọsìn Wà Fún MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àkànṣe Ìwàásù Tá A Máa Ṣe ní Oṣù November Láti Kéde Ìjọba Ọlọ́run