ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 October ojú ìwé 7
  • October 26–November 1

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 26–November 1
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 October ojú ìwé 7

October 26–November 1

Ẹ́KÍSÓDÙ 37-38

  • Orin 43 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ohun Tí Pẹpẹ Àgọ́ Ìjọsìn Wà Fún”: (10 min.)

    • Ẹk 37:25​—Ibi Mímọ́ ni wọ́n gbé pẹpẹ tùràrí sí (it-1 82 ¶3)

    • Ẹk 37:29​—Wọ́n po àwọn èròjà tí wọ́n fi ṣe tùràrí mímọ́ pọ̀ dáadáa (it-1 1195)

    • Ẹk 38:1​—Inú àgbàlá àgọ́ ìjọsìn ni wọ́n gbé pẹpẹ ẹbọ sísun sí (it-1 82 ¶1)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 37:​1, 10, 25​—Kí nìdí tó fi jẹ́ pé igi bọn-ọ̀n-ní ni wọ́n fi ṣe àgọ́ ìjọsìn? (it-1 36)

    • Ẹk 38:8​—Kí ni ìyàtọ̀ tó wà nínú dígí tí wọ́n ń lò láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì àti tòde òní? (w15 4/1 15 ¶4)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 37:​1-24 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ọ̀kan lára ìtẹ̀jáde wa tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde, tó sọ̀rọ̀ nípa kókó tí onílé sọ. (th ẹ̀kọ́ 12)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 199 ¶8-9 (th ẹ̀kọ́ 7)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 67

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • “Àkànṣe Ìwàásù Tá A Máa Ṣe ní Oṣù November Láti Kéde Ìjọba Ọlọ́run”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò nígbà àkọ́kọ́ ti oṣù November.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy orí 138

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 22 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́