ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 November ojú ìwé 4
  • November 16-22

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 16-22
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 November ojú ìwé 4

November 16-22

LÉFÍTÍKÙ 4-5

  • Orin 84 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ohun Tó Dáa Jù Ni Kó O Fún Jèhófà”: (10 min.)

    • Le 5:​5, 6​—Àwọn tó bá dẹ́ṣẹ̀ máa ń fi ọ̀dọ́ àgùntàn tàbí ewúrẹ́ rú ẹbọ ẹ̀bi (it-2 527 ¶9)

    • Le 5:7​—Tágbára ẹnì kan ò bá gbé àgùntàn tàbí ewúrẹ́, ó lè fi ẹyẹ oriri méjì tàbí ọmọ ẹyẹlé méjì rúbọ (w09 6/1 26 ¶3)

    • Le 5:11​—Àwọn tí ò bá lówó tí wọ́n á fi ra ẹyẹ oriri méjì tàbí ọmọ ẹyẹlé méjì lè lo ìyẹ̀fun ìdá mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà (w09 6/1 26 ¶4)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Le 5:1​—Báwo la ṣe lè fi ohun tó wà nínú ẹsẹ yìí sílò? (w16.02 24 ¶14)

    • Le 5:15, 16​—Láìmọ̀ọ́mọ̀, báwo lẹnì kan ṣe lè ‘hùwà àìṣòótọ́, kó sì ṣẹ̀ sí àwọn ohun mímọ́ Jèhófà’? (it-1 1130 ¶2)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 4:27–5:4 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ, àmọ́ Àìsáyà 9:6, 7 ni kó o kà. (th ẹ̀kọ́ 12)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ, àmọ́ Sáàmù 72:16 ni kó o kà. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 182 ¶22-23 (th ẹ̀kọ́ 19)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 81

  • Jèhófà Ràn Wá Lọ́wọ́ Láti Jọ Ṣe Iṣẹ́ Aṣáájú-Ọ̀nà fún Ọgọ́ta Ọdún: (15 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará ní ìbéèrè yìí: Àǹfààní wo ni Tikako àti Hisako ní lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà, báwo nìyẹn sì ṣe fún wọn láyọ̀? Ìṣòro wo ni Takako ní, kí ló sì ràn án lọ́wọ́ láti fara dà á? Àwọn nǹkan wo ló ń fún wọn láyọ̀ tó sì ń mú kí wọ́n ní ìtẹ́lọ́rùn? Báwo làwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ṣe ṣẹ sàwọn arábìnrin yìí lára: Òwe 25:11; Oníwàásù 12:1; Hébérù 6:10?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) rr “Lẹ́tà Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí” àti “Àlàyé Nípa Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí”

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 95 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́