November Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé November 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ November 2-8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́KÍSÓDÙ 39-40 Mósè Tẹ̀ Lé Ìtọ́ni Tí Jèhófà Fún Un November 9-15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 1-3 Ìdí Tí Wọ́n Fi Ń Mú Ọrẹ Wá MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI ‘Ẹyọ Owó Kéékèèké Méjì’ Tó Níye Lórí November 16-22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 4-5 Ohun Tó Dáa Jù Ni Kó O Fún Jèhófà November 23-29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 6-7 Ohun Tá A Mú Wá Láti Dúpẹ́ November 30–December 6 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 8-9 Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà Wọ́n MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Máa Fi Tẹlifóònù Wàásù