ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 November ojú ìwé 6
  • Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà Wọ́n

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà Wọ́n
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Wọ́n “Ń Tọ Ọ̀dọ́ Àgùntàn Náà Lẹ́yìn Ṣáá”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • “Ẹrú” Tí ó Jẹ́ Olóòótọ́ Àti Olóye
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • “Ní Ti Tòótọ́, Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ Àti Olóye?”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2013
  • Ta Ni Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye?
    Àwọn Wo Ló Ń Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà Lóde Òní?
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 November ojú ìwé 6

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 8-9

Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà Wọ́n

8:6-9, 12; 9:1-5, 23, 24

Jèhófà mú kí iná já bọ́ láti ọ̀run, kó sì jó ọrẹ ẹbọ sísun tí wọ́n fi rúbọ nígbà tí wọ́n yan Áárónì àtàwọn ọmọ rẹ̀ láti di àlùfáà. Ohun tó ṣẹlẹ̀ yìí fi hàn pé Jèhófà tẹ́wọ́ gbà wọ́n. Ìyẹn sì jẹ́ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó wà níbẹ̀ lọ́jọ́ yẹn rí i pé Jèhófà fẹ́ kí wọ́n ti àwọn àlùfáà náà lẹ́yìn. Lónìí, Jésù tí Ọlọ́run ti ṣe lógo ni Àlùfáà Àgbà tó tóbi jù lọ tí Jèhófà ń lò. (Heb 9:11, 12) Lọ́dún 1919, Jésù yan díẹ̀ lára àwọn ẹni àmì òróró láti jẹ́ “ẹrú olóòótọ́ àti olóye.” (Mt 24:45) Kí ló jẹ́ kó dá wa lójú pé Ọlọ́run tẹ́wọ́ gba ẹrú olóòótọ́ náà, tó sì ń tì wọ́n lẹ́yìn?

  • Láìka báwọn èèyàn ṣe ń ta ko ẹrú yìí sí, wọ́n ṣì ń pèsè gbogbo ohun tá a nílò kí ìgbàgbọ́ wa lè máa lágbára sí i

  • Bí Jésù ṣe sọ tẹ́lẹ̀, à ń wàásù ìhìn rere “ní gbogbo ilẹ̀ ayé tí à ń gbé.”​—Mt 24:14

Kí la lè ṣe láti fi hàn pé tọkàntọkàn la fi ń ti ẹrú olóòótọ́ àti olóye lẹ́yìn?

Àwòrán: 1. Jésù Kristi tí Ọlọ́run ti ṣe lógo ń ṣàkóso ayé. 2. Ẹrú olóòótọ́ àti olóye ń ṣèpàdé lórí bí wọ́n ṣe máa pèsè oúnjẹ tẹ̀mí fún wa. 3. Arákùnrin kan ń wàásù fún ọkùnrin kan.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́