ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 November ojú ìwé 6
  • November 30–December 6

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 30–December 6
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 November ojú ìwé 6

November 30–December 6

LÉFÍTÍKÙ 8-9

  • Orin 16 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Jèhófà Tẹ́wọ́ Gbà Wọ́n”: (10 min.)

    • Le 8:​6-9, 12​—Mósè yan àwọn àlùfáà (it-1 1207)

    • Le 9:​1-5​—Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wà níbẹ̀ nígbà táwọn àlùfáà rú ẹbọ àkọ́kọ́ (it-1 1208 ¶8)

    • Le 9:​23, 24​—Jèhófà jẹ́ kí wọ́n rí i pé òun tẹ́wọ́ gba àwọn àlùfáà náà (w19.11 23 ¶13)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Le 8:6​—Kí la rí kọ́ nínú bí Jèhófà ṣe fún àwọn àlùfáà lófin pé wọ́n gbọ́dọ̀ wà ní mímọ́ tónítóní? (w14 11/15 9 ¶6)

    • Le 8:​14-17​—Nígbà tí wọ́n yan àwọn àlùfáà, kí nìdí tó fi jẹ́ pé Mósè ló rú ẹbọ tí kì í ṣe Áárónì? (it-2 437 ¶3)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 8:31–9:7 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ̀rọ̀ lórí kókó kan látinú Ilé Ìṣọ́ No. 2 2020, kó o sì fún onílé ní ìwé ìròyìn náà. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ní kí onílé lọ sórí ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bhs 84 ¶6-7 (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 58

  • “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Máa Fi Tẹlifóònù Wàásù”: (15 min.) Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) rr orí 1 ¶8-14 àti àpótí 1A

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 40 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́