ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 November ojú ìwé 3
  • November 9-15

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 9-15
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 November ojú ìwé 3

November 9-15

LÉFÍTÍKÙ 1-3

  • Orin 20 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ìdí Tí Wọ́n Fi Ń Mú Ọrẹ Wá”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Léfítíkù.]

    • Le 1:3; 2:​1, 12​—Ìdí tí wọ́n fi ń rú ẹbọ sísun àti ọrẹ ọkà (it-2 525; 528 ¶4)

    • Le 3:1​—Ìdí tí wọ́n fi ń rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ (it-2 526 ¶1)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Le 2:13​—Kí nìdí tí wọ́n fi gbọ́dọ̀ fi iyọ̀ sí gbogbo ọrẹ? (Isk 43:24; w04 5/15 22 ¶1)

    • Le 3:17​—Kí nìdí tí Jèhófà fi sọ pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò gbọ́dọ̀ jẹ ọ̀rá, ẹ̀kọ́ wo nìyẹn sì kọ́ wa? (it-1 813; w04 5/15 22 ¶2)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 1:​1-17 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, àmọ́ ẹ dá a dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, ẹ jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 53

  • “ ‘Ẹyọ Owó Kéékèèké Méjì’ Tó Níye Lórí”: (15 min.) Ìjíròrò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà ‘Wọ́n Mú Ẹ̀bùn Wá fún Jèhófà’. Ka lẹ́tà tó wá látọ̀dọ̀ ẹ̀ka ọ́fíìsì tí wọ́n fi ń dúpẹ́ àwọn ọrẹ tí wọ́n rí gbà ní ọdún iṣẹ́ ìsìn tó kọjá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jy ojú ìwé 317

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 120 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́