ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 December ojú ìwé 2
  • December 7-13

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 7-13
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 December ojú ìwé 2

December 7-13

LÉFÍTÍKÙ 10-11

  • Orin 32 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “A Gbọ́dọ̀ Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ju Ìdílé Wa Lọ”: (10 min.)

    • Le 10:1, 2​—Jèhófà pa Nádábù àti Ábíhù torí pé wọ́n rú ẹbọ tí kò yẹ (it-1 1174)

    • Le 10:4, 5​—Wọ́n gbé òkú wọn lọ sẹ́yìn ibùdó

    • Le 10:6, 7​—Jèhófà pàṣẹ fún Áárónì àtàwọn ọmọ rẹ̀ yòókù pé wọn ò gbọ́dọ̀ ṣọ̀fọ̀ wọn (w11 7/15 31 ¶16)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Le 10:​8-11​—Ẹ̀kọ́ wo la rí kọ́ nínú àwọn ẹsẹ yìí? (w14 11/15 17 ¶18)

    • Le 11:8​—Ṣé àwa Kristẹni náà ò gbọ́dọ̀ jẹ àwọn ẹran tí Òfin Mósè ká léèwọ̀? (it-1 111 ¶5)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 10:​1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè pé: Báwo ni Tóyìn ṣe dọ́gbọ́n ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ, lẹ́yìn tí onílé ṣe bíi pé ohun ò fẹ́ gbọ́? Báwo lo ṣe lè ṣàlàyé Sáàmù 1:​1, 2 fún ẹnì kan?

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Pe onílé wá sípàdé, kẹ́ ẹ sì ṣe bí ẹni wo fídíò Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 20)

  • Àsọyé: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) w11 2/15 12​—Àkòrí: Kí ló mú kí ìbínú Mósè sí Élíásárì àti Ítámárì rọlẹ̀? (th ẹ̀kọ́ 12)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 51

  • “Ìfẹ́ Ló Ń Mú Ká Fara Mọ́ Ìbáwí Jèhófà”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jẹ́ Adúróṣinṣin Bó O Ṣe Ń Fi Ọkàn Kan Sin Jèhófà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) rr orí 1 ¶15-19 àti àpótí 1B

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 15 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́