December Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé December 2020 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ December 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 10-11 A Gbọ́dọ̀ Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ju Ìdílé Wa Lọ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ìfẹ́ Ló Ń Mú Ká Fara Mọ́ Ìbáwí Jèhófà December 14-20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 12-13 Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Òfin Nípa Àrùn Ẹ̀tẹ̀ December 21-27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 14-15 Ìjọsìn Mímọ́ Gba Pé Kéèyàn Wà Ní Mímọ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Lo Àwọn Ìwé Ìròyìn Wa December 28, 2020–January 3, 2021 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÉFÍTÍKÙ 16-17 Bí Ọjọ́ Ètùtù Ṣe Kàn Ẹ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé Wàá Fẹ́ Lọ Sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere?