ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb20 December ojú ìwé 6
  • December 28, 2020–January 3, 2021

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 28, 2020–January 3, 2021
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2020
mwb20 December ojú ìwé 6

December 28, 2020–January 3, 2021

LÉFÍTÍKÙ 16-17

  • Orin 41 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Bí Ọjọ́ Ètùtù Ṣe Kàn Ẹ́”: (10 min.)

    • Le 16:12​—Lọ́nà ìṣàpẹẹrẹ, àlùfáà àgbà dúró níwájú Jèhófà (w19.11 21 ¶4)

    • Le 16:13​—Àlùfáà àgbà sun tùràrí níwájú Jèhófà (w19.11 21 ¶5)

    • Le 16:14, 15​—Lẹ́yìn náà, àlùfáà àgbà máa ṣètùtù fún ẹ̀ṣẹ̀ àwọn àlùfáà àtàwọn èèyàn tó kù (w19.11 21 ¶6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Le 16:10​—Báwo ni ohun tí wọ́n máa ń fi ewúrẹ́ Ásásélì ṣe ṣe jọra pẹ̀lú ẹbọ tí Jésù rú? (it-1 226 ¶3)

    • Le 17:10, 11​—Kí ló mú ká pinnu pé a ò ní gbẹ̀jẹ̀ sára? (w14 11/15 10 ¶10)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Le 16:​1-17(th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún ẹni náà ní ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 1 ¶1-2 (th ẹ̀kọ́ 14)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 70

  • “Ṣé Wàá Fẹ́ Lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Àwọn Míṣọ́nnárì Ń Ṣíṣẹ Kára Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) rr orí 2 ¶19-27

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 50 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́