ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 9
  • Ọlọ́run àti Kristi Jẹ́ Kí Òmìnira Ọjọ́ Iwájú Ṣeé Ṣe

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọlọ́run àti Kristi Jẹ́ Kí Òmìnira Ọjọ́ Iwájú Ṣeé Ṣe
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Ń Ràn Wá Lọ́wọ́ Lákòókò Ìṣòro
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Irú Ojú Wo Ló Yẹ Ká Máa Fi Wo Àdánwò?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Bá A Ṣe Lè Máa Láyọ̀ Tá A Bá Ń Fara Da Ìṣòro
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 9
Jésù ń wolẹ̀ láti orí ìtẹ́ rẹ̀ lọ́run, ògo ìtẹ́ Jèhófà sì wá lẹ́yìn rẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ọlọ́run àti Kristi Jẹ́ Kí Òmìnira Ọjọ́ Iwájú Ṣeé Ṣe

Ìṣòro wo lò ń bá yí lójoojúmọ́? Ṣé olórí ìdílé tó ní ojúṣe tó pọ̀ ni ẹ́? Ṣé òbí tó ń dá tọ́mọ ni ẹ́, tí ò sì rọrùn fún ẹ láti gbọ́ bùkátà? Ṣé ọmọ ilé ìwé ni ẹ́, táwọn tẹ́ ẹ jọ wà nílé ìwé sì ń halẹ̀ mọ́ ẹ? Ṣé àìlera rẹ ló mú kí nǹkan nira fún ẹ àbí o ò lè ṣe tó bó o ṣe fẹ́ mọ́ torí ara tó ń dara àgbà? Kò sẹ́ni tí ò níṣòro tó ń bá yí. Kódà ìṣòro ọ̀pọ̀ lára àwọn ará wa pọ̀ gan-an. Àmọ́, ó dá wa lójú pé a máa bọ́ láìpẹ́.​—2Kọ 4:16-18.

Bá a ṣe ń retí àsìkò yẹn, ọkàn wa balẹ̀ pé Jèhófà mọ gbogbo ohun tójú wa ń rí, ó mọyì bá a ṣe jẹ́ adúróṣinṣin tá à ń fara dà á, ó sì ní ọ̀pọ̀ nǹkan tó fẹ́ fún wa lọ́jọ́ iwájú. (Jer 29:11, 12) Jésù náà nífẹ̀ẹ́ wa. Ó fẹ́ ká fọkàn balẹ̀ bá a ṣe ń sin Jèhófà nìṣó, torí ó sọ fún wa pé: “Mo wà pẹ̀lú yín.” (Mt 28:20) Tá a bá fara balẹ̀ ronú nípa òmìnira tá a máa ní lọ́jọ́ iwájú nínú Ìjọba Ọlọ́run, ìrètí wa á dájú, ìyẹn á sì jẹ́ ká máa fara da àwọn ìṣòro tá à ń kojú.​—Ro 8:19-21.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ BÍ ÌJÌ BÁ Ń JÀ, JÉSÙ NI KÓ O TẸJÚ MỌ́!​—ÀPẸẸRẸ ÀWỌN ÌṢẸ̀LẸ̀ ỌJỌ́ Ọ̀LA, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Báwo làwa èèyàn ṣe di àjèjì sí Ọlọ́run, kí nìyẹn sì yọrí sí?

  • Kí ni Jèhófà máa ṣe fáwọn olóòótọ́ lọ́jọ́ iwájú?

  • Kí ló mú káwọn ìlérí yìí ṣeé ṣe?

  • Èwo lára àwọn ìbùkún tí Ọlọ́run ṣèlérí lọ́jọ́ iwájú ló wù ẹ́ jù?

Àwòrán: Àwọn èèyàn ń gbádùn ìbùkún Jèhófà nínú Párádísè. 1. Arábìnrin kan gbá èèyàn rẹ̀ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jíǹde mọ́ra. 2. Wọ́n ń gbádùn ọ̀pọ̀ oúnjẹ, àyíká tó tura, àlàáfíà sì wà.

Fojú inú wo bí nǹkan ṣe máa rí nínú ayé tuntun

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́