January Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé January-February 2021 January 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Má Jẹ́ Kí Ohunkóhun Ba Ìwà Mímọ́ Rẹ Jẹ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Rí I Pé Ẹ̀ Ń Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín January 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣe Ohun Tá Jẹ́ Kí Ìgbéyàwó Rẹ Lágbára Sí I January 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ohun Tí Àjọyọ̀ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́ Wa MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI À Ń Fìfẹ́ Hàn Láwọn Àpéjọ Tá À Ń Ṣe Lọ́dọọdún January 25-31 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ọdún Júbílì Ṣàpẹẹrẹ Òmìnira Ọjọ́ Iwájú MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ọlọ́run àti Kristi Jẹ́ Kí Òmìnira Ọjọ́ Iwájú Ṣeé Ṣe February 1-7 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Bá A Ṣe Lè Rí Ìbùkún Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Pinnu Láti Sin Jèhófà February 8-14 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Wà Létòlétò MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Fẹ́ Ká Wàásù fún Gbogbo Èèyàn February 15-21 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Iṣẹ́ Ìsìn Àwọn Ọmọ Léfì February 22-28 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Báwo Lo Ṣe Lè Fìwà Jọ Àwọn Násírì? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé Wàá Fẹ́ Ṣe Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣù March Tàbí April? MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ