ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 12
  • February 8-14

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • February 8-14
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 12

February 8-14

NỌ́ŃBÀ 1-2

  • Orin 123 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Wà Létòlétò”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Nọ 1:2, 3​—Kí nìdí tí Jèhófà fi ní káwọn ọmọ Ísírẹ́lì forúkọ sílẹ̀? (it-2 764)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 1:1-19 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ ẹni náà, kó o sì ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Sọ ohun tó máa bá ipò onílé mu, kó o sì ka ẹsẹ Bíbélì tó máa wọ̀ ọ́ lọ́kàn. (th ẹ̀kọ́ 12)

  • Àsọyé: (5 min.) w08 7/1 21​—Àkòrí: Kí Nìdí Tí Bíbélì Fi Sábà Máa Ń Sọ̀rọ̀ Nípa Ẹ̀yà Ísírẹ́lì Méjìlá, Nígbà Tó Jẹ́ Pé Ẹ̀yà Mẹ́tàlá Ni Wọ́n? (th ẹ̀kọ́ 7)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 57

  • “Jèhófà Fẹ́ Ká Wàásù fún Gbogbo Èèyàn”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Máa Wàásù fún Àwọn Tó Ń Sọ Èdè Míì. Mẹ́nu ba àwọn nǹkan tó wà lórí ètò ìṣiṣẹ́ JW Language®.

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 4 ¶10-17

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 1 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́