ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 6
  • January 18-24

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 18-24
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 6

January 18-24

LÉFÍTÍKÙ 22-23

  • Orin 86 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ohun Tí Àjọyọ̀ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́ Wa”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Le 22:21, 22​—Kí nìdí tó fi yẹ ká fi gbogbo ọkàn wa jẹ́ olóòótọ́ àti adúróṣinṣin sí Jèhófà? (w19.02 3 ¶3)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Le 23:9-25 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ìtẹ̀jáde tó dáhùn ìbéèrè kan tó béèrè. (th ẹ̀kọ́ 13)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 9)

  • Àsọyé: (5 min.) w07 7/15 26​—Àkòrí: Ta Ló Máa Ń Kórè Àkọ́so Ọkà Bálì Tí Wọ́n Máa Ń Gbé Wá Sínú Ibi Mímọ́? (th ẹ̀kọ́ 13)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 87

  • “À Ń Fìfẹ́ Hàn Láwọn Àpéjọ Tá À Ń Ṣe Lọ́dọọdún”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àpéjọ Àgbáyé “Ìfẹ́ Kì Í Yẹ̀ Láé”!

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 3 ¶11-20

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 9 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́