ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 15
  • February 22-28

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • February 22-28
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 15

February 22-28

NỌ́ŃBÀ 5-6

  • Orin 81 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Báwo Lo Ṣe Lè Fìwà Jọ Àwọn Násírì?”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Nọ 6:6, 7​—Kí nìdí tó fi jẹ́ pé Sámúsìn ṣì jẹ́ Násírì lẹ́yìn tó fọwọ́ kan òkú èèyàn àti tẹran tó pa? (w05 1/15 30 ¶2)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Nọ 5:1-18 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Ta Ni Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 1)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Àsọyé: (5 min.) w06 1/15 32​—Àkòrí: Ohun Pàtàkì Kan Tó Túbọ̀ Jẹ́rìí Sí I Pé Ìwé Tó Ti Pẹ́ Ni Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 13)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 76

  • “Ṣé Wàá Fẹ́ Ṣe Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣù March Tàbí April?”: (5 min.) Ìjíròrò.

  • A Máa Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Pe Àwọn Èèyàn sí Ìrántí Ikú Kristi ní Saturday, February 27: (10 min.) Ìjíròrò. Fún ẹnì kọ̀ọ̀kan ní ìwé ìkésíni náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀. Sọ ètò tí ìjọ ṣe láti kárí ìpínlẹ̀ ìwàásù yín. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a máa lò. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará pé: Ìgbà wo ló yẹ ká fi fídíò Ìrántí Ikú Jésù han onílé? Báwo la ṣe lè mọ̀ tẹ́nì kan bá nífẹ̀ẹ́ sọ́rọ̀ wa?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 5 ¶9-16

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 36 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́