ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 2
  • January 4-10

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 4-10
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 2

January 4-10

LÉFÍTÍKÙ 18-19

  • Orin 122 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Má Jẹ́ Kí Ohunkóhun Ba Ìwà Mímọ́ Rẹ Jẹ́”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Le 19:9, 10​—Kí ló fi hàn pé Ọlọ́run gba tàwọn tálákà rò nínú Òfin tó fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì? (w06 6/15 22 ¶11)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Le 18:1-15 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Àdúrà​—Sm 65:2. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Àsọyé: (5 min.) w02 2/1 29​—Àkòrí: Ṣé Àwa Kristẹni Ṣì Ń Ṣègbọràn sí Òfin Mósè Tó Ka Ìgbéyàwó Láàárín Ìbátan Léèwọ̀? (th ẹ̀kọ́ 7)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 134

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Dáàbò Bo Ọmọ Rẹ: (5 min.) Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Kó o sì sọ ẹ̀kọ́ tá a rí kọ́.​—Owe 22:3.

  • “Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Rí I Pé Ẹ̀ Ń Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Kọ́ Ilé Tó Máa Wà Pẹ́ Títí​—Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ “Ohun Búburú.”

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 2 ¶28-31, àpótí 2A àti 2B

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 96 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́