ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 2
  • Má Jẹ́ Kí Ohunkóhun Ba Ìwà Mímọ́ Rẹ Jẹ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Má Jẹ́ Kí Ohunkóhun Ba Ìwà Mímọ́ Rẹ Jẹ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ohun Tí Àjọyọ̀ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́ Wa
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ǹjẹ́ O Rántí?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 2
Inú bàbá kan ò dùn sí ohun tó rí lójú kọ̀ǹpútà ẹ̀, ó sáré gbójú kúrò, ó sì pa á dé.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Má Jẹ́ Kí Ohunkóhun Ba Ìwà Mímọ́ Rẹ Jẹ́

Jèhófà fẹ́ kí ìwà wa yàtọ̀ sí tàwọn èèyàn ayé (Le 18:3; w19.06 27 ¶10)

Jèhófà kórìíra ìwà tó burú jáì, irú bíi bíbá ìbátan ẹni lòpọ̀, ìbẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀ àti bíbá ẹranko lòpọ̀ (Le 18:6, 22, 23; w17.02 20 ¶13)

Jèhófà máa pa àwọn tó ń hùwà àìmọ́ yìí run láìpẹ́ (Le 18:24, 25; Owe 2:22; w14 7/1 7 ¶2)

Sátánì ò fẹ́ ká wọnú ayé tuntun. Àmọ́ àwọn ìlànà Jèhófà lè dáàbò bò wá ká má bàa kó sí pańpẹ́ Sátánì.

Kí la lè ṣe tá á jẹ́ kí Jèhófà mọ̀ pé a kórìíra ìṣekúṣe?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́