July 12-18
DIUTARÓNÓMÌ 13-15
Orin 38 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Di 14:21—Kí la rí kọ́ látinú Òfin tó sọ pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò gbọ́dọ̀ se ọmọ ewúrẹ́ nínú wàrà ìyá ẹ̀? (w06 4/1 31)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 13:1-18 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Ìyà—1Jo 5:19. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 6)
Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fún ẹni náà ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ Má Ṣàníyàn Láé”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Má Ṣe Jẹ́ Kí Ìfẹ́ Rẹ Yẹ̀ Láé . . . Tó O Bá Tiẹ̀ Jẹ́ Tálákà—Congo.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 10 ¶13-17, àpótí 10B àti 10D
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 71 àti Àdúrà