July Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, July-August 2021 July 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Bí Jèhófà Ṣe Fẹ́ Ká Máa Sin Òun MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Máa Fọ̀rọ̀ Ro Ara Ẹ Wò July 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Ẹ Má Ṣàníyàn Láé” July 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́ July 26–August 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ẹ̀mí Èèyàn Ṣeyebíye Lójú Jèhófà August 2-8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Òfin Tí Jèhófà Ṣe Nípa Àwọn Ẹranko Fi Hàn Pé Wọ́n Ṣe Pàtàkì Sí I MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn August 9-15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Obìnrin MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Hùwà Sáwọn Àgbà Obìnrin Bí Ìyá, Àwọn Ọ̀dọ́bìnrin Bí Ọmọ Ìyá August 16-22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Gbogbo Ìbùkún Yìí Máa . . . Bá Ọ” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Wa August 23-29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Kò Nira Jù Láti Sin Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Kò Nira Jù Láti Jẹ́ Onígboyà August 30–September 5 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ohun Tí Àpèjúwe Tó Wà Nínú Orin Onímìísí Kan Kọ́ Wa MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ