ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 July ojú ìwé 8
  • August 2-8

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 2-8
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 July ojú ìwé 8

August 2-8

DIUTARÓNÓMÌ 22-23

  • Orin 1 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Òfin Tí Jèhófà Ṣe Nípa Àwọn Ẹranko Fi Hàn Pé Wọ́n Ṣe Pàtàkì Sí I”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Di 23:19, 20​—Kí nìdí táwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi lè gba èlé lọ́wọ́ àjèjì, àmọ́ tí wọn ò lè gbà á lọ́wọ́ ọmọ Ísírẹ́lì bíi tiwọn? (it-1 600)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 23:1-14 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • “Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn”: (9 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Túbọ̀ Já Fáfá—​Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Rẹ Wọni Lọ́kàn.

  • Àsọyé: (5 min.) g 5/15 15​—Àkòrí: Ṣé Ó Burú Láti Pa Àwọn Ẹranko? (th ẹ̀kọ́ 14)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 62

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 11 ¶18-26 àti àpótí 11A

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 77 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́