September 13-19
JÓṢÚÀ 1-2
Orin 97 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí Sí Rere”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Joṣ 2:4, 5—Kí nìdí tí Ráhábù fi sọ fáwọn ọkùnrin tí ọba rán níṣẹ́ pé òun ò mọbi táwọn amí náà wà? (w04 12/1 8 ¶6)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 2:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Bíbélì—Job 26:7. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 11)
Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 16)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Máa Kọ́ Agbára Ìfòyemọ̀ Rẹ”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò “Ẹ Di Ẹ̀rí-Ọkàn Rere Mú”.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 13 ¶15-21
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 89 àti Àdúrà