September Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, September-October 2021 September 6-12 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jẹ́ Kí Jèhófà Fi “Ọwọ́ Ayérayé” Rẹ̀ Dáàbò Bò Ẹ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Lo Ìwé “Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!” Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù September 13-19 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí Sí Rere MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Kọ́ Agbára Ìfòyemọ̀ Rẹ September 20-26 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Nígbàgbọ́ MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Máa Lo Àwọn Ohun Èlò Ìwádìí September 27–October 3 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Yẹra Fáwọn Nǹkan Tí Kò Ní Láárí October 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Ìtàn Àwọn Ará Gíbíónì October 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Jẹ́ Káwọn Míì Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ October 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Tẹ̀ Lé Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo October 25-31 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Dáàbò Bo Ogún Iyebíye Tí Jèhófà Fún Ẹ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Káwọn Èèyàn Mọ̀ Pé Ayé Tuntun Ò Ní Pẹ́ Dé! MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ