ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 September ojú ìwé 12
  • October 18-24

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 18-24
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 September ojú ìwé 12

October 18-24

JÓṢÚÀ 12-14

  • Orin 69 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Máa Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Tẹ̀ Lé Jèhófà”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Joṣ 13:2, 5​—Ṣé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gba “ilẹ̀ àwọn ará Gébálì” lóòótọ́? (it-1 902-903)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 12:7-24 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Fi ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!​—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!​—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 20)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 01 kókó 5 (th ẹ̀kọ́ 18)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 84

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • “Jẹ́ Kí Jèhófà Máa Wà Níwájú Rẹ Nígbà Gbogbo”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Máa Ṣiṣẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr apá 4, orí 15 ¶1-7 àti fídíò ohun tó wà ní orí 15

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 32 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́