November 8-14
JÓṢÚÀ 20-22
Orin 120 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Èdèkòyédè Kan Tó Wáyé”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Joṣ 21:43, 44—Bó tiẹ̀ jẹ́ pé gbogbo ilẹ̀ Kénáánì kọ́ làwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́gun, kí ló fi hàn pé ohun tó wà nínú ẹsẹ yìí nímùúṣẹ? (it-1 402 ¶3)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Joṣ 20:1–21:3 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Bíbélì—Ifi 21:3, 4. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 12)
Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 14)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 15 ¶18-23
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 121 àti Àdúrà